Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 66:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ta ni ó ti gbọ́ irú nǹkan bẹ́ẹ̀ rí?Ta ni ó ti rí irú nǹkan bẹ́ẹ̀ rí?Ǹjẹ́ a le bí orílẹ̀ èdè kan níjọ́ kantàbí kí orílẹ̀ èdè lalẹ̀hù ní ìṣẹ́jú kan?Síbẹ̀síbẹ̀ Ṣíhónì bẹ̀rẹ̀ rírọbí tàìrọbíbẹ́ẹ̀ ni ó sì bí àwọn ọmọ rẹ̀.

Ka pipe ipin Àìsáyà 66

Wo Àìsáyà 66:8 ni o tọ