Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 66:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Gẹ́gẹ́ bí àwọn ọ̀run tuntun àti ayé tuntun tí mo dá yóò ṣe faradà á níwájú mi,” ni Olúwa wí, “Bẹ́ẹ̀ ni orúkọ yín àti ìrandíran yín yóò pegedé.

Ka pipe ipin Àìsáyà 66

Wo Àìsáyà 66:22 ni o tọ