Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 66:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Gbogbo àwọn tí wọ́n ya ara wọn sí mímọ́ tí wọ́n sì sọ ara wọn di mímọ́ láti lọ sínú ọgbà, tí wọ́n tẹ̀lé ẹni tí ó wà láàrin àwọn tí ó jẹ ẹran ẹlẹ́dẹ̀ àti èkúté àti àwọn ohun ìríra mìíràn ni wọn yóò bá òpin wọn pàdé papọ̀,” ni Olúwa wí.

Ka pipe ipin Àìsáyà 66

Wo Àìsáyà 66:17 ni o tọ