Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 65:3-5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

3. àwọn ènìyàn tí wọ́n bí mi nínú nígbà gbogbolójú ara mi gan an,wọ́n ń rúbọ nínú ọgbàwọ́n sì ń ṣun tùràrí lóríi pẹpẹ bíríkì;

4. wọ́n ń jókòó láàrin ibojìwọ́n sì ń lo òru wọn nínú ìṣọ́ ìkọ̀kọ̀;tí wọ́n ń jẹ ẹran ẹlẹ́dẹ̀,tí ìkòkò ọbẹ̀ wọn kún fún ẹran àìmọ́;

5. tí ó wí pé, ‘Ẹ sún mẹ́yìn; ẹ má wá sọ́dọ̀ mi,nítorí mo ti jẹ́ mímọ́ jù fún un yín!’Àwọn ènìyàn bẹ́ẹ̀ jẹ́ èéfín nínú ihò imú miiná tí ń fi gbogbo ọjọ́ jó.

Ka pipe ipin Àìsáyà 65