Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 65:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Kíyèsí i, Èmi yóò dáàwọn ọ̀run tuntun àti ayé tuntunA kì yóò rántí ohun àtẹ̀yìnwá mọ́,tàbí kí wọn wá sí ọkàn.

Ka pipe ipin Àìsáyà 65

Wo Àìsáyà 65:17 ni o tọ