Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 63:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ta nì yìí tí ó ń bọ̀ láti Édómù,láti Bósírà, pẹ̀lú aṣọ rẹ̀ tí osùn ṣe àbàwọ́n fúnTa nì yìí, tí a wọ̀ ní aṣọ ẹ̀yẹ,tí ó ń yan bọ̀ wá nínú ọláńlá agbára rẹ̀?“Èmi ni bí, tí ó ń sọ̀rọ̀ nínú òdodotí ó nípa láti gbàlà.”

Ka pipe ipin Àìsáyà 63

Wo Àìsáyà 63:1 ni o tọ