Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 62:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọn kì yóò pè ọ́ ní ìkọ̀sílẹ̀ mọ́tàbí kí wọ́n pe ilẹ̀ rẹ ní ahoro.Ṣùgbọ́n a ó máa pè ọ́ ní Hẹfísíbà,àti ilẹ̀ rẹ ní Béúlà;nítorí Olúwa yóò yọ́nú sí ọàti ilẹ̀ rẹ ni a ó gbé níyàwó.

Ka pipe ipin Àìsáyà 62

Wo Àìsáyà 62:4 ni o tọ