Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 62:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Nítorí Ṣíhónì èmi kì yóò dákẹ́,nítorí i Jérúsálẹ́mù èmi kì yóò sinmi ẹnu,títí tí òdodo rẹ̀ yóò fi tàn bí òwúrọ̀,àti ìgbàlà rẹ̀ bí i tọ́ọ̀sì tí ń jó geregere.

2. Àwọn orílẹ̀ èdè yóò rí òdodo rẹ,àti gbogbo ọba ògo rẹa ó sì máa pè ọ́ ní orúkọ mìírànèyí tí ẹnu Olúwa yóò fi fún un.

Ka pipe ipin Àìsáyà 62