Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 60:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lótìítọ́ àwọn erékùṣù bojú wò mí;ní ìṣíwájú ni àwọn ọkọ̀ ojú omi Táṣíṣì;mú àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ wá láti ọ̀nà jínjìn,pẹ̀lú fàdákà àti góòlùu wọn,fún ti ọlá Olúwa Ọlọ́run rẹ,Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì,nítorí òun ti fi ohun dídára ṣe ó lọ́ṣọ̀ọ́.

Ka pipe ipin Àìsáyà 60

Wo Àìsáyà 60:9 ni o tọ