Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 60:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ògo Lẹ́bánónì yóò wá sí ọ̀dọ̀ rẹ,igi páínì, fírì àti ṣípírẹ́sì papọ̀,láti bu ọlá fún ilé ìsìn mi;àti pé èmi yóò sì ṣe ibi ẹsẹ̀ mi lógo.

Ka pipe ipin Àìsáyà 60

Wo Àìsáyà 60:13 ni o tọ