Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 6:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ìdámẹ́wàá ṣẹ́kù lórí ilẹ̀náà, yóò sì tún pàpà padà parunṢùgbọ́n gẹ́gẹ́ bí igi tẹ́rẹ́bíńtì àti óákùti í fi kùkùté sílẹ̀ nígbà tí a bá gé wọn lulẹ̀bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ ni irúgbìn mímọ́ náà yóò di kùkùté níilẹ̀ náà.”

Ka pipe ipin Àìsáyà 6

Wo Àìsáyà 6:13 ni o tọ