Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 6:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ní ọdún tí ọba Hùṣáyà kú, mo rí Olúwa tí ó jókòó lórí ìtẹ́ tí ó ga tí a gbé sókè, ọ̀wọ́ aṣọ rẹ̀ sì kún inú tẹ́ḿpìlì.

2. Àwọn Ṣéráfù wà ní òkè rẹ̀, ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn ní ìyẹ́ mẹ́fà, wọ́n fi ìyẹ́ méjì bo ojú wọn, wọ́n fi méjì bo ẹṣẹ̀ wọn, wọ́n sí ń fi méjì fò.

3. Wọ́n sì ń kọ sí ara wọn wí pé:“Mímọ́, mímọ́, mímọ́ ni Olúwa àwọn ọmọ ogungbogbo ayé kún fún ògo rẹ̀.”

Ka pipe ipin Àìsáyà 6