Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 57:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́yìn àwọn ìlẹ̀kùn yín àti òpó ìlẹ̀kùn yínníbẹ̀ ni ẹ fi àwọn àmì òrìṣà yín sí.Ní kíkọ̀ mí sílẹ̀, ẹ sí bẹ́ẹ̀dì yín sílẹ̀,ẹ gun oríi rẹ̀ lọ, ẹ sì sí i sílẹ̀ gbagada;ẹ ṣe àdéhùn pẹ̀lú àwọn tí ẹ fẹ́ràn bẹ́ẹ̀dì wọn,ẹ̀yin sì ń wo ìhòòhò wọn.

Ka pipe ipin Àìsáyà 57

Wo Àìsáyà 57:8 ni o tọ