Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 57:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Inú bí mi nítorí ẹ̀ṣẹ̀ ọ̀kánjúà rẹ̀;mo fìyà jẹ ẹ́, mo sì fojúù mi pamọ́ ní ìbínúṣíbẹ̀, ó tẹ̀ṣíwájú nínú tinú-mi-ni-n ó ṣe ọ̀nà rẹ̀.

Ka pipe ipin Àìsáyà 57

Wo Àìsáyà 57:17 ni o tọ