Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 56:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

àwọn wọ̀nyí ni èmi yóò mú wá òkè mímọ́ mièmi ó sì fún wọn ní ayọ̀ nínú ilé àdúrà mi.Ọrẹ síṣun àti ẹbọ wọnni a ó tẹ́wọ́gbà lóríi pẹpẹ mi;nítorí a ó máa pe ilé mi níilé àdúrà fún gbogbo orílẹ̀ èdè.”

Ka pipe ipin Àìsáyà 56

Wo Àìsáyà 56:7 ni o tọ