Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 56:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

fún wọn ni Èmi yóò fún nínú tẹ́ḿpìlì àti àgbàlá rẹ̀ìrántí kan àti orúkọ kantí ó sànju àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin àti ọ̀dọ́mọbìnrinÈmi yóò fún wọn ní orúkọ ayérayétí a kì yóò ké kúrò.

Ka pipe ipin Àìsáyà 56

Wo Àìsáyà 56:5 ni o tọ