Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 55:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ̀yin yóò jáde lọ ní ayọ̀a ó sì daríi yín lọ ní àlàáfíà;òkè ńlá ńlá àti kéékèèkééyóò bú sí orin níwájúu yínàti gbogbo igi inú un pápáyóò máa pàtẹ́wọ́.

Ka pipe ipin Àìsáyà 55

Wo Àìsáyà 55:12 ni o tọ