Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 55:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gẹ́gẹ́ bí òjò àti sílóòti wálẹ̀ láti ọ̀runtí kì í sì padà sí ibẹ̀láì bomirin ilẹ̀kí ó sì mú kí ó tanná kí ó sì rudi,tó bẹ́ẹ̀ tí yóò fi mú irúgbìn fún afúnrúgbìnàti àkàrà fún ọ̀jẹun,

Ka pipe ipin Àìsáyà 55

Wo Àìsáyà 55:10 ni o tọ