Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 53:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ta ni ó ti gba ìhìn in wa gbọ́àti ta ni a ti fi apá Olúwa hàn fún?

2. Òun dàgbà ṣókè níwájúu rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí àṣẹ̀ṣẹ̀yọ èhù,àti gẹ́gẹ́ bí i gbòngbo tí ó jáde láti inú ìyàngbẹ ilẹ̀.Òun kò ní ẹwà tàbí ògo láti fàwá sọ́dọ̀ ara rẹ̀,kò sí ohun kankan nínú àbùdá rẹ̀tí ó fi yẹ kí a ṣàfẹ́ríi rẹ̀.

Ka pipe ipin Àìsáyà 53