Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 52:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Jí, jí, Ìwọ Ṣíhónì,wọ ara rẹ ní agbára.Gbé aṣọ ògo rẹ wọ̀,Ìwọ Jérúsálẹ́mù, ìlú mímọ́ n nì.Àwọn aláìkọlà àti aláìmọ́kì yóò wọ inú un rẹ mọ́.

2. Gbọn eruku rẹ kúrò;dìde ṣókè, kí o sì gúnwà, Ìwọ Jérúsálẹ́mù.Bọ́ ẹ̀wọ̀n tí ń bẹ lọ́rùn rẹ kúrò,Ìwọ ọ̀dọ́mọbìnrin ìgbékùn Ṣíhónì.

3. Nítorí èyí ni ohun tí Olúwa wí;“Ọ̀fẹ́ ni a tà ọ́,láìsanwó ni a ó sì rà ọ́ padà.”

Ka pipe ipin Àìsáyà 52