Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 51:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbé ojú rẹ sókè sí àwọn ọ̀run,wo ilẹ̀ ní ìṣàlẹ̀ ilẹ̀;Àwọn ọ̀run yóò pòórá bí èéfín,ilẹ̀ yóò sì gbó bí ẹ̀wùàwọn olùgbé inú rẹ̀ yóò kú gẹ́gẹ́ bí àwọn eṣinṣin.Ṣùgbọ́n ìgbàlà mi yóò wà títí láé,òdodo mi kì yóò yẹ̀ láé.

Ka pipe ipin Àìsáyà 51

Wo Àìsáyà 51:6 ni o tọ