Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 51:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi yóò fi lé àwọn apọ́nnílójú rẹ lọ́wọ́,àwọn tí ó wí fún ọ pé,‘Dọ̀bálẹ̀, tó bẹ́ẹ̀ tí a ó fi máa rìn lóríì rẹ.’Ìwọ náà ṣe ẹ̀yìn rẹ gẹ́gẹ́ bí ilẹ̀gẹ́gẹ́ bí òpópónà láti máa rìn lóríi rẹ̀.”

Ka pipe ipin Àìsáyà 51

Wo Àìsáyà 51:23 ni o tọ