Nítorí Olúwa àwọn ọmọ-ogun ràn mí lọ́wọ́;A kì yóò dójú tìmí.Nítorí náà ni mo ṣe gbé ojú mi ró bí Òkúta akọèmi sì mọ pé, ojú kò ní tì mí.