Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 50:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ta ni nínú yín tí ó bẹ̀rù Olúwatí ó sì ń gbọ́ràn sí ìràńṣẹ́ rẹ̀ lẹ́nu?Jẹ́ kí ẹni tí ń rìn ní òkùnkùntí kò ní ìmọ́lẹ̀,kí ó gbẹ́kẹ̀lé orúkọ Olúwakí o sì gbẹ́kẹ̀lé Ọlọ́run rẹ̀.

Ka pipe ipin Àìsáyà 50

Wo Àìsáyà 50:10 ni o tọ