Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 5:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọgbà-àjàrà Olúwa àwọn ọmọ-ogunni ilé Ísírẹ́lìàwọn ọkùnrin Júdàsì ni àyànfẹ́ ọgbà rẹ̀.Ó retí ìdájọ́ ẹ̀tọ́ ṣùgbọn, ìtàjẹ̀sílẹ̀ ni ó rí,Òun ń retí òdodo ṣùgbọ́n ó gbọ ẹkún ìpayínkeke.

Ka pipe ipin Àìsáyà 5

Wo Àìsáyà 5:7 ni o tọ