Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 5:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ìsinsìn yìí, èmi yóò sọ fún ọohun tí n ó ṣe sí ọgbà-àjàrà mi:Èmi yóò gé igi inú un rẹ̀ kúrò,a ó sì pa á run,Èmi yóò wó ògiri rẹ̀ lulẹ̀yóò sì di ìtẹ̀mọ́lẹ̀.

Ka pipe ipin Àìsáyà 5

Wo Àìsáyà 5:5 ni o tọ