Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 5:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà, ìbínú Olúwa gbóná mọ́ àwọn ènìyàn rẹ̀,ó ti gbé ọwọ́ rẹ̀ ṣókè, ó sì lù wọ́n bolẹ̀.Àwọn òkè mì tìtì,àwọn òkú sì dàbí ààtàn lójú òpópó ọ̀nà.Pẹ̀lúu gbogbo èyí, ìbínú rẹ̀ kò tíí kúrò,ọ̀wọ́ rẹ̀ sì gbé ṣókè síbẹ̀.

Ka pipe ipin Àìsáyà 5

Wo Àìsáyà 5:25 ni o tọ