Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 49:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbójú rẹ ṣókè kí o sì wò yíká;gbogbo àwọn ọmọkùnrin rẹ kórajọwọ́n sì wá sọ́dọ̀ rẹ.Níwọ̀n ìgbà tí mo bá wà láàyè,” ni Olúwa wí,“Ìwọ yóò wọ gbogbo wọ́n gẹ́gẹ́ bí ohun ọ̀ṣọ́;ìwọ yóò wọ̀ wọ́n gẹ́gẹ́ bí ìyàwó.

Ka pipe ipin Àìsáyà 49

Wo Àìsáyà 49:18 ni o tọ