Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 47:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nísinsìn yìí, tẹ́tísílẹ̀, ìwọ oníwọ̀ra ẹ̀dátí o kẹ̀tẹ̀ǹfẹ̀ nínú ààbò rẹtí o sì ń sọ fún ara rẹ pé,‘Èmi ni, kò sì sí ẹlòmìíràn lẹ́yìn mi.Èmi kì yóò di opótàbí kí n pàdánù àwọn ọmọ.’

Ka pipe ipin Àìsáyà 47

Wo Àìsáyà 47:8 ni o tọ