Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 47:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lóòótọ́ wọ́n dàbí pòpó;iná ni yóò jó wọn dànù.Wọn kò kúkú lè gba ara wọn làlọ́wọ́ agbára iná náà.Kò sí èédú láti mú ara ẹnikẹ́ni gbónáníhìnín kò sí iná tí ènìyàn le jókòó tì.

Ka pipe ipin Àìsáyà 47

Wo Àìsáyà 47:14 ni o tọ