Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 46:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Tẹ́tí sími ìwọ ilé Jákọ́bù,Gbogbo ẹ̀yin tí ó ṣẹ́kù nínú ilé Ísírẹ́lì,Ìwọ tí mo ti gbérò láti ìgbà tí o ti wà nínú oyún,tí mo sì ti ń pọ̀n láti ìgbà tí a ti bí ọ.

Ka pipe ipin Àìsáyà 46

Wo Àìsáyà 46:3 ni o tọ