Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 44:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

ta ni ó sọ nípa Ṣáírọ́ọ́ṣì pé, ‘Òun ni Olùṣọ́-àgùntàn miàti pé òun yóò ṣe ohun gbogbo tí mo fẹ́;òun yóò sọ nípa Jérúsálẹ́mù pé, “Jẹ́ kí a tún un kọ́,”àti nípa tẹ́ḿpìlì, “Jẹ́ kí a fi ìpìlẹ̀ rẹ̀ lé ilẹ̀.” ’

Ka pipe ipin Àìsáyà 44

Wo Àìsáyà 44:28 ni o tọ