Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 44:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

ẹni tí ó gbé ọ̀rọ̀ àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ jádetí ó sì mú àṣọtẹ́lẹ̀ àwọn ìránṣẹ́ rẹ wá sí ìmúṣẹ,“ẹni tí ó wí nípa ti Jérúsálẹ́mù pé,‘a ó máa gbénú un rẹ̀,’àti ní ti àwọn ìlú Júdà, ‘A ó tún un kọ́,’àti àwọn ahoro rẹ̀, ‘Èmi yóò mú un bọ̀sípò,’

Ka pipe ipin Àìsáyà 44

Wo Àìsáyà 44:26 ni o tọ