Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 44:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó ń jẹ eérú, ọkàn ẹlẹ̀tàn ni ó sì í lọ́nà;òun kò lè gba ara rẹ̀ là, tàbí kí ó wí pé“Ǹjẹ́ nǹkan tí ó wà lọ́wọ́ ọ̀tún mi yìí irọ́ kọ́?”

Ka pipe ipin Àìsáyà 44

Wo Àìsáyà 44:20 ni o tọ