Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 44:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ohun èlò ìdáná ni fún ènìyàn;díẹ̀ nínú rẹ̀ ni ó mú láti mú kíara rẹ̀ lọ́wọ́ọ́rọ́,ó dá iná ó sì fi ṣe àkàrà.Ṣùgbọ́n bákan náà ni ó ṣe òrìṣà tíó sì ń sìn ín;ó yá ère, ó sì ń forí balẹ̀ fún un.

Ka pipe ipin Àìsáyà 44

Wo Àìsáyà 44:15 ni o tọ