Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 43:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wò ó, Èmi ń ṣe ohun tuntun!Nísinsìn yìí ó ti yọ ṣókè; àbí o kò rí i bí?Èmi ń ṣe ọ̀nà kan nínú aṣálẹ̀àti odò nínú ilẹ̀ ṣíṣá.

Ka pipe ipin Àìsáyà 43

Wo Àìsáyà 43:19 ni o tọ