Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 43:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ẹ̀yin ni ẹlẹ́rìí mi,” ni Olúwa wí,“Àti ìránṣẹ́ mi tí èmi ti yàn,tó bẹ́ẹ̀ tí ẹ̀yin yóò fi mọ̀ àti tí ẹ̀yin ó fi gbà ḿi gbọ́tí yóò sì yé e yín pé èmi ni ẹni náà.Ṣáájú mi kò sí ọlọ́run tí a dá,tàbí a ó wa rí òmìíràn lẹ́yìn mi.

Ka pipe ipin Àìsáyà 43

Wo Àìsáyà 43:10 ni o tọ