Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 42:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Koríko odò títẹ̀ kan ni òun kì yóò fọ́àti òwú-àtùpà tí ń jó tan an lọlòun kì yóò fẹ́ pa.Ní òdodo ni yóò mú ìdájọ́ wá;

Ka pipe ipin Àìsáyà 42

Wo Àìsáyà 42:3 ni o tọ