Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 42:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n àwọn tí ó gbẹ́kẹ̀lé òrìṣà,tí wọ́n wí fún ère pé, ‘Ẹ̀yin ni Ọlọ́run wa,’ni a ó dá padà pẹ̀lú ìtìjú.

Ka pipe ipin Àìsáyà 42

Wo Àìsáyà 42:17 ni o tọ