Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 42:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kọ orin titun sí Olúwaìyìn rẹ̀ láti òpin ilẹ̀ ayé wá,ẹ̀yin tí ó ṣọ̀kalẹ̀ lọ sínú òkun, àtiohun gbogbo tí ń bẹ nínú rẹ̀ẹ̀yin erékùṣù, àti gbogbo àwọn tí ń gbé inú un wọn.

Ka pipe ipin Àìsáyà 42

Wo Àìsáyà 42:10 ni o tọ