Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 41:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

mo mú ọ láti ìpẹ̀kun ilẹ̀ ayé,láti kọ̀rọ̀ rẹ̀ tí ó jìnnà jùlọ ni mo ti pè ọ́.Èmi wí pé, ‘Ìwọ ni ìránṣẹ́ mi;’Èmi ti yàn ọ́ bẹ́ẹ̀ ni èmi kò sì tí ì kọ̀ ọ́ sílẹ̀.

Ka pipe ipin Àìsáyà 41

Wo Àìsáyà 41:9 ni o tọ