Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 41:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ta ni ó sọ èyí láti ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀,tí àwa kò bá fi mọ̀,tàbí ṣáájú àkókò, tí àwa kò bá fi wí pé,‘Òun sọ òtítọ́’?Ẹnikẹ́ni kò sọ nípa èyí,ẹnikẹ́ni kò sàṣọtẹ́lẹ̀ rẹ̀,ẹnikẹ́ni kò gbọ́ ọ̀rọ̀ kan láti ọ̀dọ̀ rẹ̀.

Ka pipe ipin Àìsáyà 41

Wo Àìsáyà 41:26 ni o tọ