Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 41:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Mú àwọn ère-òrìṣà rẹ wọlé láti sọ fún waohun tí yóò ṣẹlẹ̀.Sọ fún wa ohun tí àwọn nǹkan àtijọ́ jẹ́,kí àwa lè ṣe àgbéyẹ̀wò wọnkí àwa sì mọ àbájáde wọn níparí.Tàbí kí o sọ fún wa ohun tí ó ń bọ̀ wá,

Ka pipe ipin Àìsáyà 41

Wo Àìsáyà 41:22 ni o tọ