Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 41:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Kíyèsi, Èmi yóò sọ ọ́ di òòlù ìpakà,tuntun tí ó mú ti eyín rẹ̀ mu, ìwọ yóò lu àwọn òkè ńlá,ìwọ yóò fọ́ wọn túútúú,a ó sì sọ òkè kékeré di ìyàngbò.

Ka pipe ipin Àìsáyà 41

Wo Àìsáyà 41:15 ni o tọ