Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 40:29-31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

29. Ó ń fi agbára fún àwọn aláàárẹ̀ó sì fi kún agbára àwọn aláàárẹ̀.

30. Àní àwọn ọ̀dọ́ ń rẹ̀wẹ̀sì, ó ń rẹ̀ wọ́n,àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin sì ń kọsẹ̀ wọ́n ṣubú;

31. Ṣùgbọ́n àwọn tí ó gbẹ́kẹ̀lé Olúwayóò tún agbára wọn ṣe.Wọn yóò fìyẹ́ fò lókè bí idì;wọn yóò ṣáré àárẹ̀ kò ní mú wọn,wọn yóò rìn òòyì kò ní kọ́ wọn.

Ka pipe ipin Àìsáyà 40