Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 40:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gẹ́rẹ́ tí a ti gbìn wọ́n,kété tí a gbìn wọ́n,kété tí wọ́n tita ẹ̀kan nínú ilẹ̀,bẹ́ẹ̀ ni ó fẹ́ atẹ́gùn lù wọ́n gbogbo wọn sì gbẹ,bẹ́ ni ìji-líle sì gbá wọn lọ gẹ́gẹ́ bí ìyàngbò.

Ka pipe ipin Àìsáyà 40

Wo Àìsáyà 40:24 ni o tọ