Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 40:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọkùnrin kan tí ó talákà ju kí ó lè múirú ọrẹ bẹ́ẹ̀ wá,wá igi tí kò le è rà.Ó wá oníṣọ̀nà tí ó dáńtọ́láti ṣe àgbékalẹ̀ ère tí kì yóò le è ṣubú.

Ka pipe ipin Àìsáyà 40

Wo Àìsáyà 40:20 ni o tọ