Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 37:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tẹ́tísílẹ̀! Èmi yóò fi ẹ̀mí kan sínú rẹ̀ tó bẹ́ẹ̀ tí ó fi jẹ́ pé bí o bá ti gbọ́ ìròyìn kan, òun yóò padà sí orílẹ̀ èdè rẹ̀, níbẹ̀ ni n ó sì ti jẹ́ kí wọn ké e lulẹ̀ pẹ̀lú idà.’ ”

Ka pipe ipin Àìsáyà 37

Wo Àìsáyà 37:7 ni o tọ