Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 37:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó lè jẹ́ pé Olúwa Ọlọ́run rẹ yóò gbọ́ ọ̀rọ̀ ọ̀gágun ẹni tí ọ̀gá rẹ̀ ọba Ásíríà ti rán láti fi Ọlọ́run alààyè ṣe ẹlẹ́yà, àti pé òun ni yóò bá a wí nítorí àwọn ọ̀rọ̀ tí Olúwa Ọlọ́run rẹ ti gbọ́. Nítorí náà gbàdúrà fún àwọn tí ó ṣẹ́kù tí wọ́n sì wà láàyè.”

Ka pipe ipin Àìsáyà 37

Wo Àìsáyà 37:4 ni o tọ