Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àìsáyà 37:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nítorí náà, èyí ni ohun tí Olúwa wí nípa ọba Ásíríà:“Òun kì yóò wọ ìlú yìí wátàbí ta ẹyọ ọfà kan níhìn-ínÒun kì yóò wá síwájúu rẹ pẹ̀lú asàtàbí kí ó kó dágunró sílẹ̀ fún un.

Ka pipe ipin Àìsáyà 37

Wo Àìsáyà 37:33 ni o tọ